12 “Ní àkókò yẹn, Máíkẹ́lì+ máa dìde, ọmọ aládé ńlá+ tó dúró nítorí àwọn èèyàn rẹ. Àkókò wàhálà máa wáyé, èyí tí irú rẹ̀ kò wáyé rí látìgbà tí orílẹ̀-èdè ti wà títí di àkókò yẹn. Ní àkókò yẹn, àwọn èèyàn rẹ máa yè bọ́,+ gbogbo àwọn tí orúkọ wọn wà nínú ìwé.+