-
Ìfihàn 7:13, 14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ọ̀kan nínú àwọn àgbààgbà náà dáhùn, ó bi mí pé: “Àwọn wo ni àwọn tó wọ aṣọ funfun yìí,+ ibo ni wọ́n sì ti wá?” 14 Mo sọ fún un lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ pé: “Olúwa mi, ìwọ lo mọ̀ ọ́n.” Ó wá sọ fún mi pé: “Àwọn yìí ni àwọn tó wá látinú ìpọ́njú ńlá náà,+ wọ́n ti fọ aṣọ wọn, wọ́n sì ti sọ wọ́n di funfun nínú ẹ̀jẹ̀ Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà.+
-