ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 24:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 “Tí ọkùnrin kan bá fẹ́ obìnrin kan, àmọ́ tí obìnrin náà ò tẹ́ ẹ lọ́rùn torí ó rí ohun kan tí kò dáa nípa rẹ̀, kó kọ ìwé ẹ̀rí ìkọ̀sílẹ̀ fún un,+ kó fi lé e lọ́wọ́, kó sì ní kó kúrò ní ilé òun.+

  • Mátíù 19:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Àwọn Farisí wá bá a, wọ́n fẹ́ dán an wò, wọ́n sì bi í pé: “Ṣé ó bófin mu fún ọkùnrin láti kọ ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀ lórí gbogbo ẹ̀sùn?”+

  • Mátíù 19:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ó sọ fún wọn pé: “Torí pé ọkàn yín le ni Mósè ṣe yọ̀ǹda fún yín láti kọ ìyàwó yín sílẹ̀,+ àmọ́ kò rí bẹ́ẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀.+

  • Máàkù 10:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Àwọn Farisí wá sọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n fẹ́ dán an wò, wọ́n sì bi í bóyá ó bófin mu fún ọkùnrin láti kọ ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀.+

  • Máàkù 10:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Wọ́n sọ pé: “Mósè fàyè gba ká kọ ìwé ẹ̀rí láti lé e lọ, ká sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀.”+

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́