-
Mátíù 15:36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 ó mú búrẹ́dì méje àti àwọn ẹja náà, lẹ́yìn tó sì dúpẹ́, ó bù ú, ó wá bẹ̀rẹ̀ sí í fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn, àwọn ọmọ ẹ̀yìn sì fún àwọn èrò náà.+
-
-
Lúùkù 9:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Lẹ́yìn náà, ó mú búrẹ́dì márùn-ún àti ẹja méjì náà, ó wo ojú ọ̀run, ó sì súre sórí wọn. Ó wá bù ú sí wẹ́wẹ́, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn pé kí wọ́n gbé e síwájú àwọn èrò náà.
-