Máàkù 10:26, 27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ẹnu túbọ̀ yà wọ́n, wọ́n sì sọ fún un* pé: “Ta ló máa wá lè rígbàlà?”+ 27 Jésù wò wọ́n tààrà, ó sì sọ pé: “Lójú èèyàn, kò ṣeé ṣe, àmọ́ kò rí bẹ́ẹ̀ lójú Ọlọ́run, torí ohun gbogbo ṣeé ṣe fún Ọlọ́run.”+ Lúùkù 18:26, 27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àwọn tó gbọ́ èyí sọ pé: “Ta ló máa wá lè rígbàlà?”+ 27 Ó sọ pé: “Àwọn ohun tí kò ṣeé ṣe fún èèyàn ṣeé ṣe fún Ọlọ́run.”+
26 Ẹnu túbọ̀ yà wọ́n, wọ́n sì sọ fún un* pé: “Ta ló máa wá lè rígbàlà?”+ 27 Jésù wò wọ́n tààrà, ó sì sọ pé: “Lójú èèyàn, kò ṣeé ṣe, àmọ́ kò rí bẹ́ẹ̀ lójú Ọlọ́run, torí ohun gbogbo ṣeé ṣe fún Ọlọ́run.”+
26 Àwọn tó gbọ́ èyí sọ pé: “Ta ló máa wá lè rígbàlà?”+ 27 Ó sọ pé: “Àwọn ohun tí kò ṣeé ṣe fún èèyàn ṣeé ṣe fún Ọlọ́run.”+