1 Àwọn Ọba 1:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ọba sọ fún wọn pé: “Ẹ mú àwọn ìránṣẹ́ olúwa yín dání, kí ẹ sì ní kí Sólómọ́nì ọmọ mi gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́* tèmi fúnra mi,+ kí ẹ wá mú un lọ sí Gíhónì.+ Sekaráyà 9:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kún fún ayọ̀, ìwọ ọmọbìnrin Síónì. Kígbe ìṣẹ́gun, ìwọ ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù. Wò ó! Ọba rẹ ń bọ̀ lọ́dọ̀ rẹ.+ Olódodo ni, ó sì ń mú ìgbàlà bọ̀,*Ó jẹ́ onírẹ̀lẹ̀,+ ó sì ń gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,Àní ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,* ọmọ abo kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.+
33 Ọba sọ fún wọn pé: “Ẹ mú àwọn ìránṣẹ́ olúwa yín dání, kí ẹ sì ní kí Sólómọ́nì ọmọ mi gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́* tèmi fúnra mi,+ kí ẹ wá mú un lọ sí Gíhónì.+
9 Kún fún ayọ̀, ìwọ ọmọbìnrin Síónì. Kígbe ìṣẹ́gun, ìwọ ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù. Wò ó! Ọba rẹ ń bọ̀ lọ́dọ̀ rẹ.+ Olódodo ni, ó sì ń mú ìgbàlà bọ̀,*Ó jẹ́ onírẹ̀lẹ̀,+ ó sì ń gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,Àní ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,* ọmọ abo kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.+