Àìsáyà 53:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wọ́n ni ín lára,+ ó sì jẹ́ kí wọ́n fìyà jẹ òun,+Àmọ́ kò la ẹnu rẹ̀. Wọ́n mú un wá bí àgùntàn sí ibi tí wọ́n ti fẹ́ pa á,+Bí abo àgùntàn tó dákẹ́ níwájú àwọn tó ń rẹ́ irun rẹ̀,Kò sì la ẹnu rẹ̀.+ 1 Pétérù 2:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nígbà tí wọ́n sọ̀rọ̀ àbùkù sí i,*+ kò sọ̀rọ̀ àbùkù sí wọn* pa dà.+ Nígbà tó ń jìyà,+ kò bẹ̀rẹ̀ sí í halẹ̀, àmọ́ ó fi ara rẹ̀ sí ìkáwọ́ Ẹni tó ń dájọ́+ òdodo.
7 Wọ́n ni ín lára,+ ó sì jẹ́ kí wọ́n fìyà jẹ òun,+Àmọ́ kò la ẹnu rẹ̀. Wọ́n mú un wá bí àgùntàn sí ibi tí wọ́n ti fẹ́ pa á,+Bí abo àgùntàn tó dákẹ́ níwájú àwọn tó ń rẹ́ irun rẹ̀,Kò sì la ẹnu rẹ̀.+
23 Nígbà tí wọ́n sọ̀rọ̀ àbùkù sí i,*+ kò sọ̀rọ̀ àbùkù sí wọn* pa dà.+ Nígbà tó ń jìyà,+ kò bẹ̀rẹ̀ sí í halẹ̀, àmọ́ ó fi ara rẹ̀ sí ìkáwọ́ Ẹni tó ń dájọ́+ òdodo.