Mátíù 13:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ó sọ fún wọn pé: “Ẹ̀yin la yọ̀ǹda fún pé kí ẹ lóye àwọn àṣírí mímọ́+ Ìjọba ọ̀run, àmọ́ a ò yọ̀ǹda fún wọn. Lúùkù 8:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ó sọ pé: “Ẹ̀yin la yọ̀ǹda fún pé kí ẹ lóye àwọn àṣírí mímọ́ Ìjọba Ọlọ́run, àmọ́ àpèjúwe+ ló jẹ́ fún àwọn yòókù, kó lè jẹ́ pé, bí wọ́n tiẹ̀ ń wò, lásán ni wọ́n á máa wò àti pé bí wọ́n tiẹ̀ ń gbọ́, kó má ṣe yé wọn.+
11 Ó sọ fún wọn pé: “Ẹ̀yin la yọ̀ǹda fún pé kí ẹ lóye àwọn àṣírí mímọ́+ Ìjọba ọ̀run, àmọ́ a ò yọ̀ǹda fún wọn.
10 Ó sọ pé: “Ẹ̀yin la yọ̀ǹda fún pé kí ẹ lóye àwọn àṣírí mímọ́ Ìjọba Ọlọ́run, àmọ́ àpèjúwe+ ló jẹ́ fún àwọn yòókù, kó lè jẹ́ pé, bí wọ́n tiẹ̀ ń wò, lásán ni wọ́n á máa wò àti pé bí wọ́n tiẹ̀ ń gbọ́, kó má ṣe yé wọn.+