ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 8:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Wò ó! wọ́n kígbe pé: “Kí ló pa wá pọ̀, Ọmọ Ọlọ́run?+ Ṣé o wá síbí láti fìyà jẹ wá+ kí àkókò tó tó ni?”+

  • Lúùkù 4:41
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 41 Àwọn ẹ̀mí èṣù tún jáde lára ọ̀pọ̀ èèyàn, wọ́n ń kígbe, wọ́n sì ń sọ pé: “Ìwọ ni Ọmọ Ọlọ́run.”+ Àmọ́ ó bá wọn wí, kò jẹ́ kí wọ́n sọ̀rọ̀,+ torí wọ́n mọ̀ pé òun ni Kristi.+

  • Lúùkù 8:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Bó ṣe rí Jésù, ó kígbe, ó sì wólẹ̀ síwájú rẹ̀, ó wá ké jáde pé: “Kí ló pa wá pọ̀, Jésù Ọmọ Ọlọ́run Gíga Jù Lọ? Mo bẹ̀ ọ́, má ṣe dá mi lóró.”+

  • Jémíìsì 2:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 O gbà pé Ọlọ́run kan ló wà, àbí? O ṣe dáadáa gan-an ni. Àwọn ẹ̀mí èṣù pàápàá gbà, jìnnìjìnnì sì bò wọ́n.+

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́