Àìsáyà 9:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn èèyàn tó ń rìn nínú òkùnkùn Ti rí ìmọ́lẹ̀ tó mọ́lẹ̀ yòò. Ní ti àwọn tó ń gbé ilẹ̀ tó ṣókùnkùn biribiri,Ìmọ́lẹ̀ ti tàn sórí wọn.+ Mátíù 4:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àwọn èèyàn tó jókòó sínú òkùnkùn rí ìmọ́lẹ̀ tó mọ́lẹ̀ yòò, ní ti àwọn tó jókòó sí agbègbè òjìji ikú, ìmọ́lẹ̀+ tàn sórí wọn.”+
2 Àwọn èèyàn tó ń rìn nínú òkùnkùn Ti rí ìmọ́lẹ̀ tó mọ́lẹ̀ yòò. Ní ti àwọn tó ń gbé ilẹ̀ tó ṣókùnkùn biribiri,Ìmọ́lẹ̀ ti tàn sórí wọn.+
16 Àwọn èèyàn tó jókòó sínú òkùnkùn rí ìmọ́lẹ̀ tó mọ́lẹ̀ yòò, ní ti àwọn tó jókòó sí agbègbè òjìji ikú, ìmọ́lẹ̀+ tàn sórí wọn.”+