-
Jòhánù 20:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Lẹ́yìn tó sọ èyí, ó yíjú pa dà, ó sì rí Jésù tó dúró síbẹ̀, àmọ́ kò mọ̀ pé Jésù ni.+
-
-
Jòhánù 21:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Àmọ́ bí ilẹ̀ ṣe ń mọ́ bọ̀, Jésù dúró sí etíkun, ṣùgbọ́n àwọn ọmọ ẹ̀yìn ò mọ̀ pé Jésù ni.+
-