ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Lúùkù 24:15, 16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Bí wọ́n ṣe jọ ń sọ̀rọ̀, tí wọ́n sì ń jíròrò àwọn nǹkan yìí, Jésù fúnra rẹ̀ sún mọ́ wọn, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í bá wọn rìn, 16 àmọ́ a ò jẹ́ kí wọ́n dá a mọ̀.+

  • Lúùkù 24:30, 31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Bó ṣe ń bá wọn jẹun,* ó mú búrẹ́dì, ó súre sí i, ó bù ú, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í fún wọn.+ 31 Ìgbà yẹn ni ojú wọn là rekete, wọ́n sì dá a mọ̀; àmọ́ ó pòórá láàárín wọn.+

  • Jòhánù 21:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Àmọ́ bí ilẹ̀ ṣe ń mọ́ bọ̀, Jésù dúró sí etíkun, ṣùgbọ́n àwọn ọmọ ẹ̀yìn ò mọ̀ pé Jésù ni.+

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́