Jóẹ́lì 2:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Lẹ́yìn ìyẹn, èmi yóò tú ẹ̀mí mi + sára onírúurú èèyàn,Àwọn ọmọ yín lọ́kùnrin àti lóbìnrin yóò sì máa sọ tẹ́lẹ̀,Àwọn àgbà ọkùnrin yín yóò máa lá àlá. Àwọn ọ̀dọ́kùnrin yín yóò sì máa rí ìran.+ Jòhánù 14:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Màá béèrè lọ́wọ́ Baba, ó sì máa fún yín ní olùrànlọ́wọ́* míì tó máa wà pẹ̀lú yín títí láé,+ Ìṣe 1:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nígbà tó ń bá wọn ṣèpàdé, ó pàṣẹ fún wọn pé: “Ẹ má ṣe kúrò ní Jerúsálẹ́mù,+ àmọ́ ẹ dúró de ohun tí Baba ti ṣèlérí,+ èyí tí ẹ gbọ́ lẹ́nu mi; 5 lóòótọ́, Jòhánù fi omi batisí, àmọ́ a ó fi ẹ̀mí mímọ́ batisí yín+ láìpẹ́ ọjọ́.” Ìṣe 2:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ní ọjọ́ Àjọyọ̀ Pẹ́ńtíkọ́sì,+ gbogbo wọn wà níbì kan náà, bí àjọyọ̀ náà ṣe ń lọ lọ́wọ́. Ìṣe 2:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 gbogbo wọn wá kún fún ẹ̀mí mímọ́,+ wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í sọ oríṣiríṣi èdè,* bí ẹ̀mí ṣe mú kí wọ́n máa sọ̀rọ̀.+
28 Lẹ́yìn ìyẹn, èmi yóò tú ẹ̀mí mi + sára onírúurú èèyàn,Àwọn ọmọ yín lọ́kùnrin àti lóbìnrin yóò sì máa sọ tẹ́lẹ̀,Àwọn àgbà ọkùnrin yín yóò máa lá àlá. Àwọn ọ̀dọ́kùnrin yín yóò sì máa rí ìran.+
4 Nígbà tó ń bá wọn ṣèpàdé, ó pàṣẹ fún wọn pé: “Ẹ má ṣe kúrò ní Jerúsálẹ́mù,+ àmọ́ ẹ dúró de ohun tí Baba ti ṣèlérí,+ èyí tí ẹ gbọ́ lẹ́nu mi; 5 lóòótọ́, Jòhánù fi omi batisí, àmọ́ a ó fi ẹ̀mí mímọ́ batisí yín+ láìpẹ́ ọjọ́.”
4 gbogbo wọn wá kún fún ẹ̀mí mímọ́,+ wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í sọ oríṣiríṣi èdè,* bí ẹ̀mí ṣe mú kí wọ́n máa sọ̀rọ̀.+