ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Róòmù 2:28, 29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Nítorí ẹni tó jẹ́ Júù ní òde kì í ṣe Júù,+ bẹ́ẹ̀ ni ìdádọ̀dọ́* kì í ṣe ohun tó wà ní òde ara.+ 29 Àmọ́ ẹni tó jẹ́ Júù ní inú ni Júù,+ ìdádọ̀dọ́* rẹ̀ sì jẹ́ ti ọkàn+ nípa ẹ̀mí, kì í ṣe nípa àkọsílẹ̀ òfin.+ Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni ìyìn ẹni yẹn ti wá, kì í ṣe láti ọ̀dọ̀ èèyàn.+

  • Róòmù 9:7, 8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe torí pé wọ́n jẹ́ ọmọ* Ábúráhámù+ ni gbogbo wọn fi jẹ́ ọmọ; kàkà bẹ́ẹ̀, “Látọ̀dọ̀ Ísákì ni ọmọ* rẹ yóò ti wá.”+ 8 Ìyẹn ni pé, àwọn ọmọ nípa tara kì í ṣe àwọn ọmọ Ọlọ́run lóòótọ́,+ àmọ́ àwọn ọmọ tó wá nípasẹ̀ ìlérí+ ni a kà sí ọmọ.*

  • Gálátíà 3:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ẹ kúkú mọ̀ pé àwọn tó rọ̀ mọ́ ìgbàgbọ́ ni ọmọ Ábúráhámù.+

  • Gálátíà 3:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Yàtọ̀ síyẹn, bí ẹ bá jẹ́ ti Kristi, ẹ jẹ́ ọmọ* Ábúráhámù lóòótọ́,+ ajogún+ nípasẹ̀ ìlérí.+

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́