-
Róòmù 15:18, 19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Torí pé mi ò ní sọ nǹkan míì àfi àwọn ohun tí Kristi ti ṣe nípasẹ̀ mi kí àwọn orílẹ̀-èdè lè wá di onígbọràn, nípa ọ̀rọ̀ àti ìṣe mi, 19 pẹ̀lú agbára àwọn iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu,*+ pẹ̀lú agbára ẹ̀mí Ọlọ́run, tó fi jẹ́ pé láti Jerúsálẹ́mù títí mo fi lọ yí ká dé Ílíríkónì ni mo ti wàásù ìhìn rere nípa Kristi+ kúnnákúnná.
-