Ìṣe 22:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Júù+ ni mí, ìlú Tásù ní Sìlíṣíà+ ni wọ́n ti bí mi, àmọ́ ìlú yìí ni mo ti gba ẹ̀kọ́ lọ́dọ̀* Gàmálíẹ́lì,+ wọ́n fi Òfin àwọn baba ńlá ìgbàanì dá mi lẹ́kọ̀ọ́ lọ́nà àìgbagbẹ̀rẹ́,+ mo sì jẹ́ onítara fún Ọlọ́run bí gbogbo yín ṣe jẹ́ lónìí yìí.+
3 “Júù+ ni mí, ìlú Tásù ní Sìlíṣíà+ ni wọ́n ti bí mi, àmọ́ ìlú yìí ni mo ti gba ẹ̀kọ́ lọ́dọ̀* Gàmálíẹ́lì,+ wọ́n fi Òfin àwọn baba ńlá ìgbàanì dá mi lẹ́kọ̀ọ́ lọ́nà àìgbagbẹ̀rẹ́,+ mo sì jẹ́ onítara fún Ọlọ́run bí gbogbo yín ṣe jẹ́ lónìí yìí.+