Ìṣe 5:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Àmọ́ Farisí kan tó ń jẹ́ Gàmálíẹ́lì + dìde nínú Sàhẹ́ndìrìn; olùkọ́ Òfin tí gbogbo èèyàn kà sí ni, ó sì pàṣẹ pé kí wọ́n mú àwọn ọkùnrin náà lọ síta fúngbà díẹ̀.
34 Àmọ́ Farisí kan tó ń jẹ́ Gàmálíẹ́lì + dìde nínú Sàhẹ́ndìrìn; olùkọ́ Òfin tí gbogbo èèyàn kà sí ni, ó sì pàṣẹ pé kí wọ́n mú àwọn ọkùnrin náà lọ síta fúngbà díẹ̀.