-
Ìṣe 23:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, àwọn Júù gbìmọ̀ pọ̀, wọ́n sì fi ègún de ara wọn, pé àwọn ò ní jẹ, àwọn ò sì ní mu títí àwọn á fi pa Pọ́ọ̀lù.