Ìṣe 21:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Pọ́ọ̀lù wá sọ pé: “Ní tòótọ́, Júù ni mí,+ láti Tásù+ ní Sìlíṣíà, ọmọ ìlú kan tó gbajúmọ̀.* Torí náà, mo bẹ̀ ọ́, jẹ́ kí n bá àwọn èèyàn náà sọ̀rọ̀.” Ìṣe 22:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Júù+ ni mí, ìlú Tásù ní Sìlíṣíà+ ni wọ́n ti bí mi, àmọ́ ìlú yìí ni mo ti gba ẹ̀kọ́ lọ́dọ̀* Gàmálíẹ́lì,+ wọ́n fi Òfin àwọn baba ńlá ìgbàanì dá mi lẹ́kọ̀ọ́ lọ́nà àìgbagbẹ̀rẹ́,+ mo sì jẹ́ onítara fún Ọlọ́run bí gbogbo yín ṣe jẹ́ lónìí yìí.+
39 Pọ́ọ̀lù wá sọ pé: “Ní tòótọ́, Júù ni mí,+ láti Tásù+ ní Sìlíṣíà, ọmọ ìlú kan tó gbajúmọ̀.* Torí náà, mo bẹ̀ ọ́, jẹ́ kí n bá àwọn èèyàn náà sọ̀rọ̀.”
3 “Júù+ ni mí, ìlú Tásù ní Sìlíṣíà+ ni wọ́n ti bí mi, àmọ́ ìlú yìí ni mo ti gba ẹ̀kọ́ lọ́dọ̀* Gàmálíẹ́lì,+ wọ́n fi Òfin àwọn baba ńlá ìgbàanì dá mi lẹ́kọ̀ọ́ lọ́nà àìgbagbẹ̀rẹ́,+ mo sì jẹ́ onítara fún Ọlọ́run bí gbogbo yín ṣe jẹ́ lónìí yìí.+