Jòhánù 10:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Jésù sì ń rìn nínú tẹ́ńpìlì ní ọ̀dẹ̀dẹ̀* Sólómọ́nì.+ Ìṣe 5:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Yàtọ̀ síyẹn, ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu* ló ń ṣẹlẹ̀ látọwọ́ àwọn àpọ́sítélì láàárín àwọn èèyàn;+ gbogbo wọn sì máa ń pé jọ nínú Ọ̀dẹ̀dẹ̀* Sólómọ́nì.+
12 Yàtọ̀ síyẹn, ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu* ló ń ṣẹlẹ̀ látọwọ́ àwọn àpọ́sítélì láàárín àwọn èèyàn;+ gbogbo wọn sì máa ń pé jọ nínú Ọ̀dẹ̀dẹ̀* Sólómọ́nì.+