1 Pétérù 2:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Torí ó dáa tí ẹnì kan bá fara da ìnira,* tó sì jìyà tí kò tọ́ sí i nítorí kó lè ní ẹ̀rí ọkàn rere lójú Ọlọ́run.+ 1 Pétérù 3:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ẹ ní ẹ̀rí ọkàn rere,+ kó lè jẹ́ pé nínú ohunkóhun tí wọ́n bá ti sọ̀rọ̀ yín láìdáa, ìwà rere tí ẹ̀ ń hù torí ẹ jẹ́ ọmọlẹ́yìn Kristi+ máa jẹ́ kí ojú ti àwọn tó ń sọ̀rọ̀ yín láìdáa.+
19 Torí ó dáa tí ẹnì kan bá fara da ìnira,* tó sì jìyà tí kò tọ́ sí i nítorí kó lè ní ẹ̀rí ọkàn rere lójú Ọlọ́run.+
16 Ẹ ní ẹ̀rí ọkàn rere,+ kó lè jẹ́ pé nínú ohunkóhun tí wọ́n bá ti sọ̀rọ̀ yín láìdáa, ìwà rere tí ẹ̀ ń hù torí ẹ jẹ́ ọmọlẹ́yìn Kristi+ máa jẹ́ kí ojú ti àwọn tó ń sọ̀rọ̀ yín láìdáa.+