Róòmù 13:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Torí náà, ìdí pàtàkì wà tó fi yẹ kí ẹ máa tẹrí ba, kì í ṣe nítorí ìrunú yẹn nìkan, àmọ́ ó jẹ́ nítorí ẹ̀rí ọkàn+ yín pẹ̀lú.
5 Torí náà, ìdí pàtàkì wà tó fi yẹ kí ẹ máa tẹrí ba, kì í ṣe nítorí ìrunú yẹn nìkan, àmọ́ ó jẹ́ nítorí ẹ̀rí ọkàn+ yín pẹ̀lú.