Òwe 10:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹni tó ń rìn nínú ìwà títọ́ yóò máa rìn nínú ààbò,+Àmọ́ àṣírí ẹni tó ń sọ ọ̀nà ara rẹ̀ di wíwọ́ yóò tú.+ 2 Kọ́ríńtì 10:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nítorí kì í ṣe ẹni tó ń dámọ̀ràn ara rẹ̀ ni a tẹ́wọ́ gbà,+ bí kò ṣe ẹni tí Jèhófà* dámọ̀ràn.+ 1 Tímótì 5:24, 25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Àwọn kan wà tí ẹ̀ṣẹ̀ wọn máa ń hàn sí ọ̀pọ̀ èèyàn, ó sì máa ń yọrí sí ìdájọ́ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, àmọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àwọn míì máa ń hàn síta nígbà tó bá yá.+ 25 Bákan náà, iṣẹ́ rere máa ń hàn síta,+ a ò sì lè fi àwọn tí kò hàn síta pa mọ́ lọ títí.+
9 Ẹni tó ń rìn nínú ìwà títọ́ yóò máa rìn nínú ààbò,+Àmọ́ àṣírí ẹni tó ń sọ ọ̀nà ara rẹ̀ di wíwọ́ yóò tú.+
24 Àwọn kan wà tí ẹ̀ṣẹ̀ wọn máa ń hàn sí ọ̀pọ̀ èèyàn, ó sì máa ń yọrí sí ìdájọ́ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, àmọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àwọn míì máa ń hàn síta nígbà tó bá yá.+ 25 Bákan náà, iṣẹ́ rere máa ń hàn síta,+ a ò sì lè fi àwọn tí kò hàn síta pa mọ́ lọ títí.+