1 Kọ́ríńtì 4:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí náà, ẹ má ṣèdájọ́+ ohunkóhun ṣáájú àkókò tó yẹ, títí Olúwa yóò fi dé. Yóò mú àwọn ohun ìkọ̀kọ̀ inú òkùnkùn wá sínú ìmọ́lẹ̀, á sì jẹ́ kí a mọ èrò ọkàn àwọn èèyàn, lẹ́yìn náà, kálukú á gba ìyìn rẹ̀ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run.+ 2 Tímótì 2:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Sa gbogbo ipá rẹ kí o lè rí ìtẹ́wọ́gbà Ọlọ́run, kí o jẹ́ òṣìṣẹ́ tí kò ní ohunkóhun tó máa tì í lójú, tó ń lo ọ̀rọ̀ òtítọ́ bó ṣe yẹ.+
5 Nítorí náà, ẹ má ṣèdájọ́+ ohunkóhun ṣáájú àkókò tó yẹ, títí Olúwa yóò fi dé. Yóò mú àwọn ohun ìkọ̀kọ̀ inú òkùnkùn wá sínú ìmọ́lẹ̀, á sì jẹ́ kí a mọ èrò ọkàn àwọn èèyàn, lẹ́yìn náà, kálukú á gba ìyìn rẹ̀ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run.+
15 Sa gbogbo ipá rẹ kí o lè rí ìtẹ́wọ́gbà Ọlọ́run, kí o jẹ́ òṣìṣẹ́ tí kò ní ohunkóhun tó máa tì í lójú, tó ń lo ọ̀rọ̀ òtítọ́ bó ṣe yẹ.+