1 Tímótì 6:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Kí àwọn tó jẹ́ ẹrú* máa ní ọ̀wọ̀ tó jinlẹ̀ fún àwọn olúwa wọn,+ kí àwọn èèyàn má bàa sọ̀rọ̀ àbùkù nípa orúkọ Ọlọ́run àti ẹ̀kọ́ rẹ̀.+ 1 Pétérù 2:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Kí àwọn ìránṣẹ́ máa tẹrí ba fún àwọn ọ̀gá wọn pẹ̀lú ìbẹ̀rù tó yẹ,+ kì í ṣe fún àwọn tó jẹ́ ẹni rere, tó sì ń gba tẹni rò nìkan, àmọ́ fún àwọn tó ṣòroó tẹ́ lọ́rùn pẹ̀lú.
6 Kí àwọn tó jẹ́ ẹrú* máa ní ọ̀wọ̀ tó jinlẹ̀ fún àwọn olúwa wọn,+ kí àwọn èèyàn má bàa sọ̀rọ̀ àbùkù nípa orúkọ Ọlọ́run àti ẹ̀kọ́ rẹ̀.+
18 Kí àwọn ìránṣẹ́ máa tẹrí ba fún àwọn ọ̀gá wọn pẹ̀lú ìbẹ̀rù tó yẹ,+ kì í ṣe fún àwọn tó jẹ́ ẹni rere, tó sì ń gba tẹni rò nìkan, àmọ́ fún àwọn tó ṣòroó tẹ́ lọ́rùn pẹ̀lú.