Fílípì 1:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ní báyìí, ẹ̀yin ará, mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé àwọn ohun tó ṣẹlẹ̀ sí mi ti mú kí ìhìn rere tẹ̀ síwájú, 13 tó fi jẹ́ pé gbogbo èèyàn mọ̀+ nípa àwọn ìdè ẹ̀wọ̀n mi+ nítorí Kristi láàárín gbogbo Ẹ̀ṣọ́ Ọba àti gbogbo àwọn yòókù.
12 Ní báyìí, ẹ̀yin ará, mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé àwọn ohun tó ṣẹlẹ̀ sí mi ti mú kí ìhìn rere tẹ̀ síwájú, 13 tó fi jẹ́ pé gbogbo èèyàn mọ̀+ nípa àwọn ìdè ẹ̀wọ̀n mi+ nítorí Kristi láàárín gbogbo Ẹ̀ṣọ́ Ọba àti gbogbo àwọn yòókù.