Mátíù 7:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Ẹ máa ṣọ́ra fún àwọn wòlíì èké+ tó ń wá sọ́dọ̀ yín nínú àwọ̀ àgùntàn,+ àmọ́ tó jẹ́ pé ọ̀yánnú ìkookò ni wọ́n ní inú.+ Ìṣe 20:29, 30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Mo mọ̀ pé lẹ́yìn tí mo bá lọ, àwọn aninilára ìkookò máa wọlé sáàárín yín,+ wọn ò sì ní fọwọ́ pẹ̀lẹ́ mú agbo, 30 àwọn kan máa dìde láàárín yín, wọ́n á sọ àwọn ọ̀rọ̀ békebèke láti fa àwọn ọmọ ẹ̀yìn sẹ́yìn ara wọn.+
15 “Ẹ máa ṣọ́ra fún àwọn wòlíì èké+ tó ń wá sọ́dọ̀ yín nínú àwọ̀ àgùntàn,+ àmọ́ tó jẹ́ pé ọ̀yánnú ìkookò ni wọ́n ní inú.+
29 Mo mọ̀ pé lẹ́yìn tí mo bá lọ, àwọn aninilára ìkookò máa wọlé sáàárín yín,+ wọn ò sì ní fọwọ́ pẹ̀lẹ́ mú agbo, 30 àwọn kan máa dìde láàárín yín, wọ́n á sọ àwọn ọ̀rọ̀ békebèke láti fa àwọn ọmọ ẹ̀yìn sẹ́yìn ara wọn.+