14 pé kí o pa àṣẹ náà mọ́ láìní àbààwọ́n àti láìlẹ́gàn títí di ìgbà tí Olúwa wa Jésù Kristi máa fara hàn,+ 15 èyí tí ẹni tó jẹ́ aláyọ̀ àti Ọba Alágbára Gíga kan ṣoṣo máa fi hàn nígbà tí àwọn àkókò rẹ̀ bá tó. Òun ni Ọba àwọn ọba àti Olúwa àwọn olúwa,+