-
2 Tímótì 2:24, 25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Torí pé kò yẹ kí ẹrú Olúwa máa jà, àmọ́ ó yẹ kó máa hùwà jẹ́jẹ́* sí gbogbo èèyàn,+ kí ó kúnjú ìwọ̀n láti kọ́ni, kó máa kó ara rẹ̀ níjàánu tí wọ́n bá ṣe ohun tí kò dáa sí i,+ 25 kó máa fi ìwà tútù tọ́ àwọn tó ń ṣàtakò sọ́nà.+ Bóyá Ọlọ́run lè mú kí wọ́n ronú pìwà dà,* kí wọ́n sì wá ní ìmọ̀ tó péye nípa òtítọ́,+
-