Òwe 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ìdáhùn pẹ̀lẹ́* máa ń mú kí ìbínú rọlẹ̀,+Àmọ́ ọ̀rọ̀ líle* ń ru ìbínú sókè.+ Kólósè 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Nítorí náà, gẹ́gẹ́ bí àyànfẹ́ Ọlọ́run,+ ẹ̀yin tí ẹ jẹ́ mímọ́ àti olùfẹ́, ẹ fi ìfẹ́ oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ ti àánú,+ inú rere, ìrẹ̀lẹ̀,*+ ìwà tútù+ àti sùúrù+ wọ ara yín láṣọ. 1 Tímótì 6:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àmọ́, ìwọ tí o jẹ́ èèyàn Ọlọ́run, sá fún àwọn nǹkan yìí. Ṣùgbọ́n máa wá òdodo, ìfọkànsin Ọlọ́run, ìgbàgbọ́, ìfẹ́, ìfaradà àti ìwà tútù.+ Títù 3:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 kí wọ́n má sọ̀rọ̀ ẹnì kankan láìdáa, kí wọ́n má ṣe jẹ́ oníjà, kí wọ́n máa fòye báni lò,+ kí wọ́n jẹ́ oníwà tútù sí gbogbo èèyàn.+
12 Nítorí náà, gẹ́gẹ́ bí àyànfẹ́ Ọlọ́run,+ ẹ̀yin tí ẹ jẹ́ mímọ́ àti olùfẹ́, ẹ fi ìfẹ́ oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ ti àánú,+ inú rere, ìrẹ̀lẹ̀,*+ ìwà tútù+ àti sùúrù+ wọ ara yín láṣọ.
11 Àmọ́, ìwọ tí o jẹ́ èèyàn Ọlọ́run, sá fún àwọn nǹkan yìí. Ṣùgbọ́n máa wá òdodo, ìfọkànsin Ọlọ́run, ìgbàgbọ́, ìfẹ́, ìfaradà àti ìwà tútù.+
2 kí wọ́n má sọ̀rọ̀ ẹnì kankan láìdáa, kí wọ́n má ṣe jẹ́ oníjà, kí wọ́n máa fòye báni lò,+ kí wọ́n jẹ́ oníwà tútù sí gbogbo èèyàn.+