Sáàmù 34:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Jáwọ́ nínú ohun búburú, kí o sì máa ṣe rere;+Máa wá àlàáfíà, kí o sì máa lépa rẹ̀.+ Róòmù 12:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Tó bá ṣeé ṣe, nígbà tó bá ti jẹ́ pé ọwọ́ yín ló wà, ẹ wà ní àlàáfíà pẹ̀lú gbogbo èèyàn.+ Róòmù 14:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Nítorí náà, ẹ jẹ́ kí a máa lépa àwọn ohun tó ń mú kí àlàáfíà wà+ àti àwọn ohun tó ń gbé ẹnì kejì wa ró.+
19 Nítorí náà, ẹ jẹ́ kí a máa lépa àwọn ohun tó ń mú kí àlàáfíà wà+ àti àwọn ohun tó ń gbé ẹnì kejì wa ró.+