Ẹ́kísódù 16:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jẹ mánà fún ogójì (40) ọdún,+ títí wọ́n fi dé ilẹ̀ kan tí àwọn èèyàn ń gbé.+ Wọ́n jẹ mánà títí wọ́n fi dé ààlà ilẹ̀ Kénáánì.+ Nọ́ńbà 32:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jèhófà bínú gidigidi sí Ísírẹ́lì, ó sì mú kí wọ́n fi ogójì (40) ọdún+ rìn kiri nínú aginjù, títí gbogbo ìran tó ń hùwà ibi lójú Jèhófà fi pa run.+ Sáàmù 95:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nígbà tí àwọn baba ńlá yín dán mi wò;+Wọ́n pè mí níjà, bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n ti rí àwọn iṣẹ́ mi.+
35 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jẹ mánà fún ogójì (40) ọdún,+ títí wọ́n fi dé ilẹ̀ kan tí àwọn èèyàn ń gbé.+ Wọ́n jẹ mánà títí wọ́n fi dé ààlà ilẹ̀ Kénáánì.+
13 Jèhófà bínú gidigidi sí Ísírẹ́lì, ó sì mú kí wọ́n fi ogójì (40) ọdún+ rìn kiri nínú aginjù, títí gbogbo ìran tó ń hùwà ibi lójú Jèhófà fi pa run.+