Ìfihàn 7:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Mo sọ fún un lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ pé: “Olúwa mi, ìwọ lo mọ̀ ọ́n.” Ó wá sọ fún mi pé: “Àwọn yìí ni àwọn tó wá látinú ìpọ́njú ńlá náà,+ wọ́n ti fọ aṣọ wọn, wọ́n sì ti sọ wọ́n di funfun nínú ẹ̀jẹ̀ Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà.+
14 Mo sọ fún un lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ pé: “Olúwa mi, ìwọ lo mọ̀ ọ́n.” Ó wá sọ fún mi pé: “Àwọn yìí ni àwọn tó wá látinú ìpọ́njú ńlá náà,+ wọ́n ti fọ aṣọ wọn, wọ́n sì ti sọ wọ́n di funfun nínú ẹ̀jẹ̀ Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà.+