1 Àwọn Ọba 7:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Lẹ́yìn náà, ó fi irin ṣe Òkun.*+ Ó rí ribiti, fífẹ̀ ẹnu rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá, gíga rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún, okùn ìdíwọ̀n ọgbọ̀n (30) ìgbọ̀nwọ́ ló sì lè yí i ká.*+ Ìfihàn 4:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ohun kan tó rí bí òkun tó ń dán bíi gíláàsì+ wà níwájú ìtẹ́ náà, ó dà bíi kírísítálì. Ẹ̀dá alààyè mẹ́rin+ tí ojú kún iwájú àti ẹ̀yìn wọn wà ní àárín ìtẹ́ náà* àti yí ká ìtẹ́ náà.
23 Lẹ́yìn náà, ó fi irin ṣe Òkun.*+ Ó rí ribiti, fífẹ̀ ẹnu rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá, gíga rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún, okùn ìdíwọ̀n ọgbọ̀n (30) ìgbọ̀nwọ́ ló sì lè yí i ká.*+
6 Ohun kan tó rí bí òkun tó ń dán bíi gíláàsì+ wà níwájú ìtẹ́ náà, ó dà bíi kírísítálì. Ẹ̀dá alààyè mẹ́rin+ tí ojú kún iwájú àti ẹ̀yìn wọn wà ní àárín ìtẹ́ náà* àti yí ká ìtẹ́ náà.