-
Ìṣe 15:28, 29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Nítorí ẹ̀mí mímọ́+ àti àwa fúnra wa ti fara mọ́ ọn pé ká má ṣe dì kún ẹrù yín, àyàfi àwọn ohun tó pọn dandan yìí: 29 láti máa ta kété sí àwọn ohun tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà,+ láti máa ta kété sí ẹ̀jẹ̀,+ sí ohun tí wọ́n fún lọ́rùn pa*+ àti sí ìṣekúṣe.*+ Tí ẹ bá ń yẹra fún àwọn nǹkan yìí délẹ̀délẹ̀, ẹ ó láásìkí. Kí ara yín ó le o!”*
-