Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Sámúẹ́lì 2 SÁMÚẸ́LÌ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ 1 Dáfídì gbọ́ nípa ikú Sọ́ọ̀lù (1-16) Orin arò tí Dáfídì kọ nítorí Sọ́ọ̀lù àti Jónátánì (17-27) 2 Dáfídì di ọba Júdà (1-7) Íṣí-bóṣétì di ọba Ísírẹ́lì (8-11) Ogun tó wáyé láàárín ilé Dáfídì àti ilé Sọ́ọ̀lù (12-32) 3 Ilé Dáfídì ń di alágbára sí i (1) Àwọn ọmọkùnrin Dáfídì (2-5) Ábínérì lọ dara pọ̀ mọ́ Dáfídì (6-21) Jóábù pa Ábínérì (22-30) Dáfídì ṣọ̀fọ̀ Ábínérì (31-39) 4 Wọ́n pa Íṣí-bóṣétì (1-8) Dáfídì ní kí wọ́n pa àwọn apààyàn náà (9-12) 5 Dáfídì di ọba lórí gbogbo Ísírẹ́lì (1-5) Wọ́n gba Jerúsálẹ́mù (6-16) Síónì, Ìlú Dáfídì (7) Dáfídì ṣẹ́gun àwọn Filísínì (17-25) 6 Wọ́n gbé Àpótí náà wá sí Jerúsálẹ́mù (1-23) Úsà gbá Àpótí náà mú, ó sì kú (6-8) Míkálì pẹ̀gàn Dáfídì (16, 20-23) 7 Dáfídì kò ní lè kọ́ tẹ́ńpìlì (1-7) Ọlọ́run bá Dáfídì dá májẹ̀mú ìjọba (8-17) Àdúrà ìdúpẹ́ tí Dáfídì gbà (18-29) 8 Àwọn tí Dáfídì ṣẹ́gun (1-14) Ìjọba Dáfídì (15-18) 9 Ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tí Dáfídì ní sí Méfíbóṣétì (1-13) 10 Ó ṣẹ́gun Ámónì àti Síríà (1-19) 11 Dáfídì àti Bátí-ṣébà ṣe àgbèrè (1-13) Dáfídì ṣètò pé kí wọ́n pa Ùráyà (14-25) Dáfídì fi Bátí-ṣébà ṣe aya (26, 27) 12 Nátánì bá Dáfídì wí (1-15a) Ọmọ Bátí-ṣébà kú (15b-23) Bátí-ṣébà bí Sólómọ́nì (24, 25) Dáfídì gba ìlú Rábà tó jẹ́ ti àwọn ọmọ Ámónì (26-31) 13 Ámínónì fipá bá Támárì lò pọ̀ (1-22) Ábúsálómù pa Ámínónì (23-33) Ábúsálómù sá lọ sí Géṣúrì (34-39) 14 Jóábù àti obìnrin ará Tèkóà (1-17) Dáfídì já ọgbọ́nkọ́gbọ́n Jóábù (18-20) Dáfídì gbà kí Ábúsálómù pa dà (21-33) 15 Ọ̀tẹ̀ àti rìkíṣí tí Ábúsálómù dì (1-12) Dáfídì sá kúrò ní Jerúsálẹ́mù (13-30) Áhítófẹ́lì dara pọ̀ mọ́ Ábúsálómù (31) Ọba rán Húṣáì láti ta ko Áhítófẹ́lì (32-37) 16 Síbà sọ̀rọ̀ Méfíbóṣétì láìdáa (1-4) Ṣíméì gbé Dáfídì ṣépè (5-14) Ábúsálómù gba Húṣáì sọ́dọ̀ (15-19) Ìmọ̀ràn Áhítófẹ́lì (20-23) 17 Húṣáì sọ ìmọ̀ràn Áhítófẹ́lì di asán (1-14) Wọ́n kìlọ̀ fún Dáfídì; ó bọ́ lọ́wọ́ Ábúsálómù (15-29) Básíláì àti àwọn míì pèsè oúnjẹ (27-29) 18 Wọ́n ṣẹ́gun Ábúsálómù, wọ́n sì pa á (1-18) Dáfídì gbọ́ nípa ikú Ábúsálómù (19-33) 19 Dáfídì ṣọ̀fọ̀ Ábúsálómù (1-4) Jóábù bá Dáfídì wí (5-8a) Dáfídì pa dà sí Jerúsálẹ́mù (8b-15) Ṣíméì tọrọ ìdáríjì (16-23) Méfíbóṣétì fi hàn pé òun ò ṣẹ̀ (24-30) Básíláì gbayì (31-40) Àríyànjiyàn láàárín àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì (41-43) 20 Ṣébà dìtẹ̀; Jóábù pa Ámásà (1-13) Wọ́n lépa Ṣébà, wọ́n sì gé orí rẹ̀ (14-22) Ìjọba Dáfídì (23-26) 21 Àwọn ará Gíbíónì gbẹ̀san lára ilé Sọ́ọ̀lù (1-14) Àwọn ogun tó wáyé láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àti àwọn Filísínì (15-22) 22 Dáfídì yin Ọlọ́run nítorí ìgbàlà tí ó ṣe (1-51) “Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi” (2) Jèhófà jẹ́ adúróṣinṣin sí àwọn adúróṣinṣin (26) 23 Ọ̀rọ̀ tí Dáfídì sọ kẹ́yìn (1-7) Ohun tí àwọn jagunjagun Dáfídì tó lákíkanjú gbé ṣe (8-39) 24 Dáfídì dẹ́ṣẹ̀ torí pé ó ka èèyàn (1-14) Àjàkálẹ̀ àrùn pa 70,000 (15-17) Dáfídì mọ pẹpẹ (18-25) Kò sí ẹbọ tí kì í náni ní nǹkan (24)