Ojú ìwé 2
Ọgbà Àgbáyé kan Àlá Tàbí Ìṣẹ̀lẹ̀ Gidi Lọ́jọ́ Iwájú? 3-10
Àwọn ènìyàn fẹ́ràn àwọn ọgbà alálàáfíà tí ó ní àwọn òdòdó, ewéko, odò, àti adágún nínú. Kà nípa bí gbogbo ilẹ̀ ayé yóò ṣe di ọgbà rírẹwà kan.
Kíkó Àwọn Ọmọdé Nífà Ìbálòpọ̀—Ìṣòro Kan Tí Ó Kárí Ayé 11
A ti pè é ní “ìsọ̀rí ìwà ọ̀daràn àìlọ́làjú, tí ó sì ń ríni lára jù lọ.” Kí ni ojútùú náà?
A Ha Lè Máa Bá Ìgbéyàwó Kan Lọ Lẹ́yìn Ìhùwà Àìtọ́ Bí? 23
Nígbà tí alábàáṣègbéyàwó kan bá jẹ́ aláìṣòótọ́, a ha gbọ́dọ̀ tú ìdè ìgbéyàwó náà bí?