Ojú ìwé 2
Ṣópin Ti Dé Bá Ẹ̀rù Ohun Ìjà Ọ̀gbálẹ̀gbáràwé Tó Ń Bà Wá Ni? 3-11
Nígbà tí Ọ̀tẹ̀ Abẹ́lẹ̀ parí, ọ̀pọ̀ èèyàn ló dunnú pé aráyé ti bọ́ nínú bíbẹ̀rù ogun ọ̀gbálẹ̀gbáràwé. Àmọ́, ọ̀wọ́ àwọn àpilẹ̀kọ yìí gbé díẹ̀ lára ìdí tí ewu tó so mọ́ ohun ìjà ọ̀gbálẹ̀gbáràwé fi pọ̀ ju bí ọ̀pọ̀ èèyàn ṣe rò lọ.
Ojú Ìwòye Bíbéli 12
Kí Ni Ojúṣe Ẹni Rere Nílùú?
Sísin Ọlọ́run ní Bèbè Ikú 14
Wọ́n fòòró ẹ̀mí rẹ̀, wọ́n sì fi í sẹ́wọ̀n àti àgọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́ fún ọ̀pọ̀ ọdún ṣùgbọ́n ó fara dà á. Ka ìtàn tí ń gbéni ró nípa ọkùnrin ará Áfíríkà yìí.
[Àwọn àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Àwòrán ìbúgbàù tó wà lẹ́yìn ìwé: UNITED NATIONS/PHOTO BY SYGMA