Àtẹ Apá 1
Ìgbà Ayé Énọ́kù Sígbà Ayé Àwọn Onídàájọ́
Ṣáájú Ìkún Omi
ÈÈYÀN |
DÉÈTÌ |
|---|---|
Ádámù |
4026-3096 Ṣ.S.K. |
Énọ́kù |
3404-3039 Ṣ.S.K. |
Nóà |
2970-2020 Ṣ.S.K. |
Lẹ́yìn Ìkún Omi
ÈÈYÀN |
DÉÈTÌ |
|---|---|
Ábúráhámù |
2018-1843 Ṣ.S.K. |
Sérà |
2008-1881 Ṣ.S.K. |
Rèbékà |
1900*-1775* Ṣ.S.K. |
Jékọ́bù |
1858-1711 Ṣ.S.K. |
Jósẹ́fù |
1767-1657 Ṣ.S.K. |
Ṣífúrà, Púà, Ámúrámù, Jókébédì, Míríámùa |
1645*-1474* Ṣ.S.K. |
Mósè |
1593-1473 Ṣ.S.K. |
Kélẹ́bù |
1552-1450* Ṣ.S.K. |
Jóṣúà |
1560*-1450* Ṣ.S.K. |
Ráhábù |
1500*-1400* Ṣ.S.K. |
*Déètì tó ṣeé ṣe kó jẹ́.
Ìgbà Ayé Àwọn Onídàájọ́
ÈÈYÀN |
DÉÈTÌ |
|---|---|
Náómì, Rúùtù, Dèbórà, Bárákì, Jáẹ́lì, Gídíónì, Sámúsìn, Jẹ́fútà àti ọmọbìnrin ẹ̀b |
1450*-1120* Ṣ.S.K. |
Sámúẹ́lì |
1180*-1080* Ṣ.S.K. |
*Déètì tó ṣeé ṣe kó jẹ́.
Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì
2370 Ṣ.S.K.
Ìkún Omi
1943 Ṣ.S.K.
Májẹ̀mú tí Ọlọ́run bá Ábúráhámù dá bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́
1728 Ṣ.S.K.
Ìdílé Jékọ́bù dé Íjíbítì
1600c Ṣ.S.K.
ÌJỌBA TÓ Ń ṢÀKÓSO AYÉ: Íjíbítì
1513 Ṣ.S.K.
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní Íjíbítì
1473 Ṣ.S.K.
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dé ilẹ̀ Kénáánì
1117 Ṣ.S.K.
Sámúẹ́lì fi Sọ́ọ̀lù jọba
a Ìlà yìí jẹ́ ká mọ ìgbà tí gbogbo àwọn èèyàn yìí gbé ayé.
b Ìlà yìí jẹ́ ká mọ àwọn tó gbé ayé láàárín ọgọ́rùn-ún mẹ́ta ó lé ọgbọ̀n (330) ọdún. Kò sí ẹni tó lò tó ọgọ́rùn-ún mẹ́ta ó lé ọgbọ̀n (330) ọdún láyé lára wọn, a ò sì mọ ọjọ́ ìbí tàbí ọjọ́ tí wọ́n kú gangan.
c Déètì tó ṣeé ṣe kó jẹ́.