Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
August 15, 2009
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
September 28–October 4
Ọlọ́run Ló Fún Aráyé Ní Ìrètí Ìyè Àìnípẹ̀kun Lórí Ilẹ̀ Ayé
OJÚ ÌWÉ 3
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 76, 222
October 5-11
Ṣé Ìyè Àìnípẹ̀kun Lórí Ilẹ̀ Ayé Jẹ́ Ìrètí Tó Wà Fáwọn Kristẹni?
OJÚ ÌWÉ 7
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 187, 15
October 12-18
Bí Ìrètí Ìyè Àìnípẹ̀kun Lórí Ilẹ̀ Ayé Ṣe Pa Dà Wá Sójú Táyé
OJÚ ÌWÉ 12
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 4, 220
October 19-25
OJÚ ÌWÉ 18
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 114, 85
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 sí 3 OJÚ ÌWÉ 3 sí 16
Àwọn àpilẹ̀kọ yìí ṣàlàyé ohun tí Ìwé Mímọ́ sọ nípa ìrètí ìyè àìnípẹ̀kun lórí ilẹ̀ ayé. Àwọn àpilẹ̀kọ yìí á jẹ́ kí ìrètí tó fìyàtọ̀ sáàárín àwa Kristẹni tòótọ́ àtàwọn oníṣọ́ọ̀ṣì yìí túbọ̀ dá ọ lójú. Ìgbàgbọ́ rẹ yóò lágbára sí i, èyí á sì jẹ́ kó o máa láyọ̀ nígbà gbogbo, á sì tún jẹ́ kó o nígboyà láti sọ̀rọ̀ nípa ìrètí tó o ní fáwọn ẹlòmíì.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 4 OJÚ ÌWÉ 18 sí 22
Àpilẹ̀kọ yìí jíròrò ọ̀nà mẹ́ta tá a lè gbà dúró nínú ìfẹ́ Ọlọ́run. (Júúdà 21) A lè ṣe bẹ́ẹ̀ nípa (1) nínífẹ̀ẹ́ àwọn tí Jèhófà fẹ́ràn, (2) bíbọ̀wọ̀ fáwọn aláṣẹ àti (3) sísapá láti wà ní mímọ́ lójú Jèhófà.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Ó Rí Àwọn Ìṣúra Tó Wà ní Ìpamọ́
OJÚ ÌWÉ 16
OJÚ ÌWÉ 23
‘Jèhófà Ti Mú Kí Ojú Rẹ̀ Tàn sí Wọn Lára’
OJÚ ÌWÉ 24
Má Ṣe Jẹ́ Kí Ọkàn Rẹ Pínyà ní “Ọjọ́ Ìhìn Rere” Yìí
OJÚ ÌWÉ 28
Ṣé O Ti Sìn Nígbà Kan Rí? Ǹjẹ́ O Tún Lè Sìn Lẹ́ẹ̀kan Sí I?
OJÚ ÌWÉ 30