ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÚÙKÙ 23-24 Ṣe Tán Láti Dárí Jini 24:34 Ta ni mo gbọ́dọ̀ dárí jì? Kí ni gbólóhùn náà “ṣe tán láti dárí jini” túmọ̀ sí? (Sm 86:5) Jèhófà àti Ọmọ rẹ̀ máa ń kíyè sí ọkàn ẹni tó bá dẹ́ṣẹ̀ tó sì wá yí pa dà, kí wọ́n lè dárí jì í.