APÁ 3 Bíi Ti Orí Ìwé Ohun tó dá lé: Ohun tí Ọlọ́run fẹ́ káwọn tó ń jọ́sìn rẹ̀ máa ṣe Ẹ̀KỌ́ 34 Báwo La Ṣe Lè Fi Hàn Pé A Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà? 35 Bá A Ṣe Lè Ṣe Ìpinnu Tó Dáa 36 Jẹ́ Olóòótọ́ Nínú Ohun Gbogbo 37 Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Iṣẹ́ àti Owó 38 Fi Hàn Pé O Mọyì Ẹ̀mí 39 Ohun Tí Ọlọ́run Sọ Nípa Ẹ̀jẹ̀ 40 Bá A Ṣe Lè Jẹ́ Mímọ́ Lójú Ọlọ́run 41 Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìbálòpọ̀? 42 Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Àwọn Tó Lọ́kọ Tàbí Aya Àtàwọn Tí Kò Ní 43 Ṣó Yẹ Káwọn Kristẹni Máa Mu Ọtí? 44 Ṣé Gbogbo Ayẹyẹ Ni Inú Ọlọ́run Dùn Sí? 45 Ohun Tó Túmọ̀ Sí Láti Má Ṣe Dá Sí Ogun àti Ọ̀rọ̀ Òṣèlú 46 Ìdí Tó Fi Yẹ Kó O Ya Ara Rẹ Sí Mímọ́ Fún Jèhófà Kó O sì Ṣèrìbọmi 47 Ṣé O Ti Múra Tán Láti Ṣèrìbọmi?