Diutarónómì 33:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Aláyọ̀ ni ọ́, ìwọ Ísírẹ́lì!+ Ta ló dà bí rẹ,+Àwọn èèyàn tó ń gbádùn ìgbàlà Jèhófà,+Apata tó ń dáàbò bò ọ́,+Àti idà ọlá ńlá rẹ? Àwọn ọ̀tá rẹ máa ba búrúbúrú níwájú rẹ,+Wàá sì rìn lórí ẹ̀yìn* wọn.” 2 Sámúẹ́lì 22:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọlọ́run mi ni àpáta+ mi, ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata+ mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò+ mi,*Àti ibi tí mo lè sá sí,+ olùgbàlà+ mi; ìwọ tí o gbà mí lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá. Sáàmù 144:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Òun ni ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ àti ibi ààbò mi,Ibi gíga mi tó láàbò àti olùgbàlà mi,Apata mi àti Ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,+Ẹni tó ń tẹ àwọn èèyàn lórí ba sábẹ́ mi.+
29 Aláyọ̀ ni ọ́, ìwọ Ísírẹ́lì!+ Ta ló dà bí rẹ,+Àwọn èèyàn tó ń gbádùn ìgbàlà Jèhófà,+Apata tó ń dáàbò bò ọ́,+Àti idà ọlá ńlá rẹ? Àwọn ọ̀tá rẹ máa ba búrúbúrú níwájú rẹ,+Wàá sì rìn lórí ẹ̀yìn* wọn.”
3 Ọlọ́run mi ni àpáta+ mi, ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata+ mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò+ mi,*Àti ibi tí mo lè sá sí,+ olùgbàlà+ mi; ìwọ tí o gbà mí lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá.
2 Òun ni ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ àti ibi ààbò mi,Ibi gíga mi tó láàbò àti olùgbàlà mi,Apata mi àti Ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,+Ẹni tó ń tẹ àwọn èèyàn lórí ba sábẹ́ mi.+