Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
September 1, 2010
Kí Nìdí Táwọn Èèyàn Fi Ń Ṣe Ohun Tó Burú?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Kí Nìdí Táwọn Èèyàn Fi Ń Ṣe Ohun Tó Burú?
5 Ó Dájú Pé Ìwà Ibi Máa Dópin!
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
14 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Ó Fún Wa Lómìnira Láti Ṣe Ohun Tó Wù Wá
15 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
25 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
30 Abala Àwọn Ọ̀dọ́—Ọlọ́run Kì Í Ṣe Ojúsàájú
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
18 Kí Ló Ti Jẹ́ Àbájáde Ẹ̀kọ́ Ìsìn Calvin Láti Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta Ọdún?
22 Ṣé Ọlọ́run Béèrè Pé Ká Máa Jẹ́wọ́ Ẹ̀ṣẹ̀?
26 Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà—Yóò Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́