ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jémíìsì 2
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jémíìsì

      • Ojúsàájú jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ (1-13)

        • Ìfẹ́ ni ọba òfin (8)

      • Ìgbàgbọ́ láìsí àwọn iṣẹ́ jẹ́ òkú (14-26)

        • Àwọn ẹ̀mí èṣù gbà, jìnnìjìnnì sì bò wọ́n (19)

        • A pe Ábúráhámù ní ọ̀rẹ́ Jèhófà (23)

Jémíìsì 2:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 5:21; Jem 3:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2002, ojú ìwé 16

    11/15/1997, ojú ìwé 13-14

Jémíìsì 2:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 13-14

Jémíìsì 2:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 19:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 13-14

Jémíìsì 2:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ga 3:28
  • +Di 1:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 14

Jémíìsì 2:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 2:9
  • +Lk 22:28-30

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 14

Jémíìsì 2:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 13:50

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 14

Jémíìsì 2:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 14

Jémíìsì 2:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 19:18; Mt 22:39; Ro 13:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 9/2019, ojú ìwé 8

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2006, ojú ìwé 29-30

    11/15/1997, ojú ìwé 14

Jémíìsì 2:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “bá yín wí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jem 2:1
  • +Le 19:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2007, ojú ìwé 28

    11/15/1997, ojú ìwé 14

Jémíìsì 2:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 27:26; Ga 3:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 14

Jémíìsì 2:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 20:14; Di 5:18
  • +Ẹk 20:13; Di 5:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 14

Jémíìsì 2:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “òfin òmìnira.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jem 1:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 14

    9/1/1996, ojú ìwé 15

Jémíìsì 2:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 21:13; Mt 5:7; 6:15; Lk 6:36

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2008, ojú ìwé 20

    9/15/2007, ojú ìwé 25

    3/1/2002, ojú ìwé 30

    11/15/1997, ojú ìwé 14

Jémíìsì 2:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Tit 3:8; Jem 1:25
  • +1Kọ 13:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 14-15

Jémíìsì 2:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “bá wà níhòòhò.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 14-15

Jémíìsì 2:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 15:7, 8; Mt 25:35, 36; Lk 3:11; Ro 12:13; 1Ti 5:4; Jem 1:27; 1Jo 3:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2001, ojú ìwé 5

    11/15/1997, ojú ìwé 14-15

Jémíìsì 2:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 7:21; Heb 10:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 28

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 14-15

Jémíìsì 2:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 15

Jémíìsì 2:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 8:28, 29; Lk 4:33, 34

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2016, ojú ìwé 28-29

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 15

Jémíìsì 2:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 15

Jémíìsì 2:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 22:9, 12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 15

Jémíìsì 2:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 11:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 15

    12/15/1995, ojú ìwé 20

Jémíìsì 2:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 15:6; Ro 4:3; Ga 3:6
  • +2Kr 20:7; Ais 41:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/1998, ojú ìwé 11-12

    11/15/1997, ojú ìwé 15

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 73-75

Jémíìsì 2:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 15-16

    2/1/1996, ojú ìwé 8

Jémíìsì 2:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 2:1, 15; 6:17; Heb 11:31

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2013, ojú ìwé 14

    11/15/1997, ojú ìwé 15-16

    12/15/1993, ojú ìwé 22-25

Jémíìsì 2:26

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “èémí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 146:4
  • +Ro 10:10; Jem 2:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 15-16

Àwọn míì

Jém. 2:11Ti 5:21; Jem 3:17
Jém. 2:3Le 19:15
Jém. 2:4Ga 3:28
Jém. 2:4Di 1:17
Jém. 2:5Ifi 2:9
Jém. 2:5Lk 22:28-30
Jém. 2:6Iṣe 13:50
Jém. 2:8Le 19:18; Mt 22:39; Ro 13:10
Jém. 2:9Jem 2:1
Jém. 2:9Le 19:15
Jém. 2:10Di 27:26; Ga 3:10
Jém. 2:11Ẹk 20:14; Di 5:18
Jém. 2:11Ẹk 20:13; Di 5:17
Jém. 2:12Jem 1:25
Jém. 2:13Owe 21:13; Mt 5:7; 6:15; Lk 6:36
Jém. 2:14Tit 3:8; Jem 1:25
Jém. 2:141Kọ 13:2
Jém. 2:16Di 15:7, 8; Mt 25:35, 36; Lk 3:11; Ro 12:13; 1Ti 5:4; Jem 1:27; 1Jo 3:17
Jém. 2:17Mt 7:21; Heb 10:24
Jém. 2:19Mt 8:28, 29; Lk 4:33, 34
Jém. 2:21Jẹ 22:9, 12
Jém. 2:22Heb 11:17
Jém. 2:23Jẹ 15:6; Ro 4:3; Ga 3:6
Jém. 2:232Kr 20:7; Ais 41:8
Jém. 2:25Joṣ 2:1, 15; 6:17; Heb 11:31
Jém. 2:26Sm 146:4
Jém. 2:26Ro 10:10; Jem 2:17
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jémíìsì 2:1-26

Lẹ́tà Jémíìsì

2 Ẹ̀yin ará mi, bí ẹ ṣe di ìgbàgbọ́ Jésù Kristi, Olúwa wa ológo mú, ṣé kì í ṣe pé ẹ tún ń ṣe ojúsàájú?+ 2 Tí ẹnì kan bá wá sí ìpàdé yín, tó wọ àwọn òrùka wúrà sí ìka rẹ̀, tó sì wọ aṣọ tó dáa gan-an, àmọ́ tí tálákà kan tó wọ aṣọ tó dọ̀tí náà wọlé wá, 3 ṣé ẹ máa fi ojúure wo ẹni tó wọ aṣọ tó dáa gan-an, tí ẹ máa sọ pé, “Jókòó síbi tó dáa yìí,” tí ẹ sì máa wá sọ fún tálákà náà pé, “Ìwọ wà lórí ìdúró” tàbí, “Jókòó síbẹ̀ yẹn lábẹ́ àpótí ìtìsẹ̀ mi”?+ 4 Tí ẹ bá ń ṣe bẹ́ẹ̀, ṣé kì í ṣe pé kẹ́lẹ́gbẹ́mẹgbẹ́ ti wà láàárín yín nìyẹn,+ tí ẹ sì ti di adájọ́ tó ń dá ẹjọ́ burúkú?+

5 Ẹ fetí sílẹ̀, ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n. Ṣebí àwọn tí aráyé kà sí tálákà ni Ọlọ́run yàn pé kí wọ́n jẹ́ ọlọ́rọ̀ nínú ìgbàgbọ́+ àti ajogún Ìjọba náà, èyí tó ṣèlérí fún àwọn tó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀?+ 6 Síbẹ̀, ẹ ti tàbùkù sí tálákà. Ṣebí àwọn ọlọ́rọ̀ ló ń ni yín lára,+ tí wọ́n sì ń fà yín lọ sí ilé ẹjọ́? 7 Ṣebí wọ́n máa ń sọ̀rọ̀ òdì sí orúkọ rere tí ẹ̀ ń jẹ́? 8 Tí ẹ bá ń mú ọba òfin ṣẹ bó ṣe wà nínú ìwé mímọ́ pé, “Kí o nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ,”+ ẹ̀ ń ṣe dáadáa gan-an ni. 9 Àmọ́ tí ẹ bá ṣì ń ṣe ojúsàájú,+ ẹ̀ṣẹ̀ lẹ̀ ń dá, òfin sì ti dá yín lẹ́bi* pé ẹlẹ́ṣẹ̀ ni yín.+

10 Torí tí ẹnikẹ́ni bá ń pa gbogbo Òfin mọ́ àmọ́ tó ṣi ẹsẹ̀ gbé nínú ọ̀kan, ó ti rú gbogbo òfin.+ 11 Torí ẹni tó sọ pé, “O ò gbọ́dọ̀ ṣe àgbèrè,”+ ló tún sọ pé, “O ò gbọ́dọ̀ pààyàn.”+ Nígbà náà, tí o ò bá ṣe àgbèrè àmọ́ tí o pààyàn, o ti di arúfin. 12 Ẹ máa sọ̀rọ̀ kí ẹ sì máa hùwà bí àwọn tí a máa fi òfin àwọn tó wà lómìnira* dá lẹ́jọ́.+ 13 Torí ẹni tí kì í ṣàánú kò ní rí àánú gbà nígbà ìdájọ́.+ Àánú máa ń borí ìdájọ́.

14 Ẹ̀yin ará mi, kí ni àǹfààní rẹ̀, tí ẹnì kan bá sọ pé òun ní ìgbàgbọ́ àmọ́ tí kò ní àwọn iṣẹ́?+ Ìgbàgbọ́ yẹn ò lè gbà á là, àbí ó lè gbà á?+ 15 Tí arákùnrin tàbí arábìnrin èyíkéyìí ò bá láṣọ,* tí wọn ò sì ní oúnjẹ tó máa tó wọn jẹ lóòjọ́, 16 síbẹ̀ tí ẹnì kan nínú yín sọ fún wọn pé, “Ẹ máa lọ ní àlàáfíà; kí ẹ rí aṣọ fi bora, kí ẹ sì yó dáadáa,” àmọ́ tí ẹ ò fún wọn ní ohun tí ara wọn nílò, àǹfààní kí ló jẹ́?+ 17 Bákan náà, ìgbàgbọ́ nìkan láìsí àwọn iṣẹ́ jẹ́ òkú.+

18 Àmọ́ ẹnì kan lè sọ pé: “Ìwọ́ ní ìgbàgbọ́, èmí sì ní àwọn iṣẹ́. Fi ìgbàgbọ́ rẹ hàn mí láìsí àwọn iṣẹ́, màá sì fi ìgbàgbọ́ mi hàn ọ́ nípa àwọn iṣẹ́ mi.” 19 O gbà pé Ọlọ́run kan ló wà, àbí? O ṣe dáadáa gan-an ni. Àwọn ẹ̀mí èṣù pàápàá gbà, jìnnìjìnnì sì bò wọ́n.+ 20 Àmọ́ ṣé o tiẹ̀ mọ̀ pé ìgbàgbọ́ kò wúlò láìsí iṣẹ́, ìwọ èèyàn lásánlàsàn? 21 Ṣebí a ka Ábúráhámù bàbá wa sí olódodo nípa àwọn iṣẹ́ lẹ́yìn tó mú Ísákì ọmọ rẹ̀ lọ sórí pẹpẹ?+ 22 Ẹ rí i pé ìgbàgbọ́ rẹ̀ hàn kedere nínú àwọn iṣẹ́ rẹ̀, àwọn iṣẹ́ rẹ̀ sì sọ ìgbàgbọ́ rẹ̀ di pípé,+ 23 a sì mú ìwé mímọ́ náà ṣẹ tó sọ pé: “Ábúráhámù ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà,* a sì kà á sí òdodo fún un,”+ a sì wá ń pè é ní ọ̀rẹ́ Jèhófà.*+

24 Ṣé ẹ wá rí i pé àwọn iṣẹ́ la fi ń ka èèyàn sí olódodo, kì í ṣe ìgbàgbọ́ nìkan. 25 Bákan náà, ṣebí àwọn iṣẹ́ ló mú kí á ka Ráhábù aṣẹ́wó pẹ̀lú sí olódodo, lẹ́yìn tó gba àwọn òjíṣẹ́ lálejò, tó sì ní kí wọ́n gba ọ̀nà míì jáde?+ 26 Lóòótọ́, bí ara láìsí ẹ̀mí* ṣe jẹ́ òkú,+ bẹ́ẹ̀ ni ìgbàgbọ́ láìsí àwọn iṣẹ́ jẹ́ òkú.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́