Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè APÁ 1 APÁ 1 Kí Jésù Tó Bẹ̀rẹ̀ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ̀ ORÍ 1 Ìkéde Méjì Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run ORÍ 2 Wọ́n Pọ́n Jésù Lé Kí Wọ́n Tó Bí I ORÍ 3 Wọ́n Bí Ẹni Tó Máa Ṣètò Ọ̀nà Sílẹ̀ ORÍ 4 Màríà Lóyún Láìṣègbéyàwó ORÍ 5 Ìgbà Wo Ni Wọ́n Bí Jésù, Ibo sì Ni Wọ́n Bí I Sí? ORÍ 6 Ọmọ Tí Ọlọ́run Ṣèlérí ORÍ 7 Àwọn Awòràwọ̀ Wá Sọ́dọ̀ Jésù ORÍ 8 Wọ́n Sá Lọ Mọ́ Ọba Burúkú Kan Lọ́wọ́ ORÍ 9 Ó Ń Dàgbà ní Násárẹ́tì ORÍ 10 Jósẹ́fù àti Ìdílé Rẹ̀ Rìnrìn Àjò Lọ sí Jerúsálẹ́mù ORÍ 11 Jòhánù Arinibọmi Ṣètò Ọ̀nà Sílẹ̀ APÁ 2 APÁ 2 Ìbẹ̀rẹ̀ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Jésù ORÍ 12 Jésù Ṣe Ìrìbọmi ORÍ 13 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Bí Jésù Ṣe Kojú Àdánwò ORÍ 14 Jésù Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ní Ọmọ Ẹ̀yìn ORÍ 15 Jésù Ṣe Iṣẹ́ Ìyanu Àkọ́kọ́ ORÍ 16 Jésù Ní Ìtara Fún Ìjọsìn Tòótọ́ ORÍ 17 Jésù Kọ́ Nikodémù Lẹ́kọ̀ọ́ ní Òru ORÍ 18 Jòhánù Ń Dín Kù, Àmọ́ Jésù Ń Pọ̀ Sí I ORÍ 19 Jésù Kọ́ Obìnrin Ará Samáríà Kan Lẹ́kọ̀ọ́ APÁ 3 APÁ 3 Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tó Ta Yọ Tí Jésù Ṣe ní Gálílì ORÍ 20 Iṣẹ́ Ìyanu Kejì ní Kánà ORÍ 21 Jésù Lọ sí Sínágọ́gù Tó Wà ní Násárẹ́tì ORÍ 22 Àwọn Ọmọ Ẹ̀yìn Mẹ́rin Di Apẹja Èèyàn ORÍ 23 Jésù Ṣe Iṣẹ́ Ìyanu ní Kápánáúmù ORÍ 24 Jésù Mú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ̀ Gbòòrò Sí I ní Gálílì ORÍ 25 Jésù Fàánú Hàn sí Adẹ́tẹ̀ Kan, Ó sì Wò Ó Sàn ORÍ 26 “A Dárí Àwọn Ẹ̀ṣẹ̀ Rẹ Jì Ọ́” ORÍ 27 Jésù Pe Mátíù ORÍ 28 Kí Nìdí Tí Àwọn Ọmọlẹ́yìn Jésù Kò Fi Gbààwẹ̀? ORÍ 29 Ṣé Èèyàn Lè Ṣe Ohun Tó Dáa Lọ́jọ́ Sábáàtì? ORÍ 30 Bí Jésù Ṣe Jẹ́ sí Baba Rẹ̀ ORÍ 31 Wọ́n Já Ọkà Jẹ Lọ́jọ́ Sábáàtì ORÍ 32 Kí Ló Bófin Mu ní Sábáàtì? ORÍ 33 Jésù Mú Àsọtẹ́lẹ̀ Àìsáyà Ṣẹ ORÍ 34 Jésù Yan Àwọn Àpọ́sítélì Méjìlá ORÍ 35 Ìwàásù Orí Òkè ORÍ 36 Ọ̀gágun Kan Fi Hàn Pé Òun Nígbàgbọ́ Tó Lágbára ORÍ 37 Jésù Jí Ọmọ Opó Kan Dìde ORÍ 38 Jòhánù Fẹ́ Gbọ́rọ̀ Látẹnu Jésù ORÍ 39 Jésù Dẹ́bi fún Ìran Aláìgbọràn ORÍ 40 Ẹ̀kọ́ Nípa Ìdáríjì ORÍ 41 Agbára Wo Ni Jésù Fi Ń Ṣe Iṣẹ́ Ìyanu? ORÍ 42 Jésù Bá Àwọn Farisí Wí ORÍ 43 Àwọn Àpèjúwe Nípa Ìjọba Ọlọ́run ORÍ 44 Jésù Mú Kí Ìjì Dáwọ́ Dúró Lórí Òkun ORÍ 45 Agbára Jésù Ju Ti Àwọn Ẹ̀mí Èṣù Lọ ORÍ 46 Obìnrin Kan Rí Ìwòsàn Nígbà Tó Fọwọ́ Kan Aṣọ Jésù ORÍ 47 Jésù Jí Ọmọbìnrin Kan Dìde! ORÍ 48 Jésù Ṣe Iṣẹ́ Ìyanu, Àmọ́ Àwọn Ará Násárẹ́tì Kò Gbà Á Gbọ́ ORÍ 49 Ó Wàásù, Ó sì Dá Àwọn Àpọ́sítélì Lẹ́kọ̀ọ́ ní Gálílì ORÍ 50 Wọ́n Ṣe Tán Láti Wàásù Láìka Àtakò Sí ORÍ 51 Wọ́n Pa Èèyàn Níbi Ayẹyẹ Ọjọ́ Ìbí Kan ORÍ 52 Ó Fi Ìwọ̀nba Búrẹ́dì àti Ẹja Bọ́ Ẹgbẹẹgbẹ̀rún Èèyàn ORÍ 53 Alákòóso Kan Tó Láṣẹ Lórí Àwọn Nǹkan Àdáyébá ORÍ 54 Jésù “Ni Oúnjẹ Ìyè” ORÍ 55 Ọ̀rọ̀ Jésù Ya Ọ̀pọ̀ Èèyàn Lẹ́nu ORÍ 56 Kí Ló Ń Sọni Di Aláìmọ́? ORÍ 57 Jésù Wo Ọmọbìnrin Kan àti Adití Kan Sàn ORÍ 58 Ó Mú Kí Búrẹ́dì Pọ̀, Ó sì Kìlọ̀ Nípa Ìwúkàrà ORÍ 59 Ta Ni Ọmọ Èèyàn? ORÍ 60 Ìran Ìyípadà Ológo ORÍ 61 Jésù Wo Ọmọkùnrin Tí Ẹ̀mí Èṣù Ń Yọ Lẹ́nu Sàn ORÍ 62 Ẹ̀kọ́ Pàtàkì Nípa Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀ ORÍ 63 Méjì Lára Ìmọ̀ràn Jésù ORÍ 64 Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Dárí Jini ORÍ 65 Jésù Ń Kóni Nígbà Tó Ń Lọ sí Jerúsálẹ́mù APÁ 4 APÁ 4 Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Jésù Pa Dà Ṣe ní Jùdíà ORÍ 66 Jésù Lọ sí Jerúsálẹ́mù Nígbà Àjọyọ̀ Àwọn Àgọ́ Ìjọsìn ORÍ 67 “Èèyàn Kankan Ò Sọ̀rọ̀ Báyìí Rí” ORÍ 68 Ọmọ Ọlọ́run Ni “Ìmọ́lẹ̀ Ayé” ORÍ 69 Ṣé Ábúráhámù Ni Bàbá Wọn Àbí Èṣù? ORÍ 70 Jésù La Ojú Ọkùnrin Kan Tí Wọ́n Bí Ní Afọ́jú ORÍ 71 Àwọn Farisí Gbọ́ Tẹnu Ọkùnrin Afọ́jú Náà ORÍ 72 Jésù Rán Àádọ́rin (70) Ọmọ Ẹ̀yìn Jáde Lọ Wàásù ORÍ 73 Ará Samáríà Kan Fi Hàn Pé Òun Láàánú ORÍ 74 Ẹ̀kọ́ Nípa Aájò Àlejò àti Àdúrà ORÍ 75 Jésù Sọ Ohun Tó Ń Fúnni Láyọ̀ ORÍ 76 Farisí Kan Gba Jésù Lálejò ORÍ 77 Jésù Sọ̀rọ̀ Nípa Ọrọ̀ ORÍ 78 Jésù Ní Kí Ìríjú Olóòótọ́ Náà Múra Sílẹ̀ ORÍ 79 Ìdí Táwọn Èèyàn Náà Fi Máa Pa Run ORÍ 80 Olùṣọ́ Àgùntàn Àtàtà àti Agbo Àgùntàn ORÍ 81 Ọ̀kan Ni Jésù àti Baba, Àmọ́ Jésù Kì Í Ṣe Ọlọ́run APÁ 5 APÁ 5 Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Jésù Pa Dà Ṣe ní Ìlà Oòrùn Jọ́dánì ORÍ 82 Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Jésù ní Pèríà ORÍ 83 Àwọn Tí Ọlọ́run Pè Síbi Àsè Kan ORÍ 84 Iṣẹ́ Kékeré Kọ́ Lẹnì Kan Máa Ṣe Kó Tó Lè Di Ọmọ Ẹ̀yìn ORÍ 85 Àwọn Áńgẹ́lì Máa Ń Yọ̀ Tí Ẹlẹ́ṣẹ̀ Kan Bá Ronú Pìwà Dà ORÍ 86 Ọmọ Tó Sọ Nù Pa Dà Wálé ORÍ 87 Múra Sílẹ̀, Kó O sì Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n ORÍ 88 Nǹkan Yí Pa Dà fún Ọkùnrin Ọlọ́rọ̀ Kan àti Lásárù ORÍ 89 Ó ń kọ́ni ní Pèríà bó ṣe ń lọ sí Jùdíà ORÍ 90 “Àjíǹde àti Ìyè” ORÍ 91 Jésù Jí Lásárù Dìde ORÍ 92 Jésù Wo Adẹ́tẹ̀ Mẹ́wàá Sàn, Ọ̀kan Pa Dà Wá Dúpẹ́ ORÍ 93 Ọlọ́run Máa Ṣí Ọmọ Èèyàn Payá ORÍ 94 Ohun Méjì Tó Ṣe Pàtàkì—Àdúrà àti Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀ ORÍ 95 Jésù Sọ̀rọ̀ Nípa Ìkọ̀sílẹ̀, Ó sì Fìfẹ́ Hàn Sáwọn Ọmọdé ORÍ 96 Jésù Dáhùn Ìbéèrè Ọ̀dọ́kùnrin Ọlọ́rọ̀ Kan ORÍ 97 Àpèjúwe Àwọn Òṣìṣẹ́ Ọgbà Àjàrà ORÍ 98 Àwọn Àpọ́sítélì Tún Ń Wá Ipò Ọlá ORÍ 99 Jésù La Ojú Àwọn Afọ́jú, Ó sì Ran Sákéù Lọ́wọ́ ORÍ 100 Àpèjúwe Mínà Mẹ́wàá APÁ 6 APÁ 6 Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Jésù Ṣe Kẹ́yìn ORÍ 101 Wọ́n Lọ Jẹun Nílé Símónì ní Bẹ́tánì 102 Ọba Gun Ọmọ Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ Wọ Jerúsálẹ́mù ORÍ 103 Jésù Fọ Tẹ́ńpìlì Mọ́ Lẹ́ẹ̀kan Sí I ORÍ 104 Lẹ́yìn Táwọn Júù Gbọ́ Ohùn Ọlọ́run, Ṣé Wọ́n Gba Jésù Gbọ́? ORÍ 105 Jésù Fi Igi Ọ̀pọ̀tọ́ Kan Kọ́ Wọn Lẹ́kọ̀ọ́ Nípa Ìgbàgbọ́ ORÍ 106 Àpèjúwe Méjì Nípa Ọgbà Àjàrà ORÍ 107 Ọba Kan Pe Àwọn Èèyàn Wá Síbi Ayẹyẹ Ìgbéyàwó ORÍ 108 Ìdáhùn Jésù Ò Jẹ́ Káwọn Ọ̀tá Rẹ̀ Rí I Mú ORÍ 109 Ó Dẹ́bi Fáwọn Aṣáájú Ìsìn Tó Ń Ta Kò Ó ORÍ 110 Ọjọ́ Tí Jésù Wá sí Tẹ́ńpìlì Kẹ́yìn ORÍ 111 Àwọn Àpọ́sítélì Ní Kí Jésù Fún Àwọn Ní Àmì ORÍ 112 Ẹ̀kọ́ Tí Àpèjúwe Wúńdíá Mẹ́wàá Kọ́ Wa ORÍ 113 Ẹ̀kọ́ Tí Àpèjúwe Tálẹ́ńtì Kọ́ Wa ORÍ 114 Kristi Ṣèdájọ́ Àgùntàn àti Ewúrẹ́ ORÍ 115 Ìrékọjá Tí Jésù Máa Ṣe Kẹ́yìn Ń Sún Mọ́lé ORÍ 116 Jésù Kọ́ Wọn Lẹ́mìí Ìrẹ̀lẹ̀ Níbi Ìrékọjá Tó Ṣe Kẹ́yìn ORÍ 117 Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa ORÍ 118 Wọ́n Jiyàn Nípa Ẹni Tó Tóbi Jù ORÍ 119 Jésù Ni Ọ̀nà, Òtítọ́ àti Ìyè ORÍ 120 Béèyàn Ṣe Lè Dà Bí Ẹ̀ka Tó Ń So Èso, Kó sì Di Ọ̀rẹ́ Jésù ORÍ 121 “Ẹ Mọ́kàn Le! Mo Ti Ṣẹ́gun Ayé” ORÍ 122 Àdúrà Tí Jésù Gbà Kẹ́yìn ní Yàrá Tó Wà Lókè ORÍ 123 Jésù Gbàdúrà Nígbà Tí Ẹ̀dùn Ọkàn Bá A ORÍ 124 Júdásì Da Jésù, Wọ́n sì Fàṣẹ Ọba Mú Jésù ORÍ 125 Wọ́n Mú Jésù Lọ Sọ́dọ̀ Ánásì àti Káyáfà ORÍ 126 Pétérù Sẹ́ Jésù Nílé Káyáfà ORÍ 127 Jésù Jẹ́jọ́ Níwájú Sàhẹ́ndìrìn àti Pílátù ORÍ 128 Pílátù àti Hẹ́rọ́dù Rí I Pé Jésù Ò Jẹ̀bi ORÍ 129 Pílátù Sọ Pé: “Ẹ Wò Ó! Ọkùnrin Náà Nìyí!” ORÍ 130 Ó Fa Jésù Lé Wọn Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Lọ Pa Á ORÍ 131 Ọba Kan Ń Jìyà Láìṣẹ̀ Lórí Òpó Igi ORÍ 132 “Ó Dájú Pé Ọmọ Ọlọ́run Ni Ọkùnrin Yìí” ORÍ 133 Wọ́n Ṣètò Òkú Jésù, Wọ́n sì Lọ Sin Ín ORÍ 134 Ọlọ́run Ti Jí Jésù Dìde, Ibojì Rẹ̀ sì Ti Ṣófo! ORÍ 135 Jésù Fara Han Ọ̀pọ̀ Èèyàn Lẹ́yìn Tó Jíǹde ORÍ 136 Ohun Tó Ṣẹlẹ̀ Létíkun Gálílì ORÍ 137 Ọ̀pọ̀ Èèyàn Ló Rí Jésù Ṣáájú Ọjọ́ Pẹ́ńtíkọ́sì ORÍ 138 Kristi Wà Lọ́wọ́ Ọ̀tún Ọlọ́run ORÍ 139 Jésù Parí Iṣẹ́ Rẹ̀, Ó sì Máa Sọ Ayé Di Párádísè Tó O Bá Fẹ́ Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù, Ó Yẹ Kó O . . . Atọ́ka Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ Atọ́ka Àwọn Àpèjúwe (Àkàwé) Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Kan Nípa Mèsáyà Àwọn Ibi Tí Jésù Gbé Tó sì Ti Kọ́ni