SÁÀMÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-
Onídàájọ́ òdodo ni Jèhófà
“Ṣe ìdájọ́ mi, Jèhófà” (8)
-
Jèhófà dìde láti gbé ìgbésẹ̀
Àwọn ọ̀rọ̀ Ọlọ́run mọ́ (6)
-
Ọba tí Ọlọ́run fòróró yàn rí ìgbàlà
Àwọn kan gbẹ́kẹ̀ lé kẹ̀kẹ́ ẹṣin àti àwọn ẹṣin, “àmọ́ àwa ń ké pe orúkọ Jèhófà” (7))
-
Ọba ológo wọ ẹnubodè
“Jèhófà ló ni ayé” (1)
-
Ọlọ́run gbọ́ àdúrà onísáàmù
“Jèhófà ni agbára mi àti apata mi” (7)
-
Ọ̀fọ̀ yí pa dà di ìdùnnú
Ojú rere Ọlọ́run wà títí ọjọ́ ayé (5)
-
Àdúrà ìrànlọ́wọ́ nígbà tí ọ̀tá yí mi ká
“Ọlọ́run ni olùrànlọ́wọ́ mi” (4)
-
Ọlọ́run kan wà tó ń ṣèdájọ́ ayé
Àdúrà pé kí ìyà jẹ àwọn ẹni burúkú (6-8)
-
Ọlọ́run jẹ́ ilé gogoro alágbára sí àwọn ọ̀tá
“Màá wà nínú àgọ́ rẹ” (4)
-
Ààbò lọ́wọ́ àtakò tó fara sin
“Ọlọ́run yóò ta wọ́n lọ́fà” (7)
-
Ó bẹ Ọlọ́run pé kó tètè wá ran òun lọ́wọ́
“Tètè wá ràn mí lọ́wọ́” (5)
-
Ọlọ́run ń ṣe ìdájọ́ bó ṣe tọ́
Àwọn ẹni burúkú yóò mu ohun tó wà nínú ife Jèhófà (8)
-
Síónì, ìlú Ọlọ́run tòótọ́
Àwọn tí a bí ní Síónì (4-6)
-
Jèhófà jẹ́ Olùgbàlà àti Onídàájọ́ òdodo
Jèhófà jẹ́ kí a mọ ìgbàlà rẹ̀ (2, 3)
-
Kí gbogbo orílẹ̀-èdè yin Jèhófà
Ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tí Ọlọ́run ní pọ̀ gan-an (2)
-
Mọrírì ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tó ṣeyebíye
-
Wọ́n gbógun tì í, àmọ́ wọn ò ṣẹ́gun
Ojú ti àwọn tó kórìíra Síónì (5)
-
Mo ní ìtẹ́lọ́rùn bí ọmọ tí a gba ọmú lẹ́nu rẹ̀
Mi ò lé nǹkan ńláńlá (1)
-
Wọ́n ń yin Ọlọ́run ní òròòru
“Ẹ gbé ọwọ́ yín sókè nínú ìjẹ́mímọ́” (2)